Ìdàgbàsókè alaílẹ́gbẹ́ nílò ọgbọ́n ènìyàn nítorí gbogbo ìdàgbàsókè dá lórí iṣẹ́ ṣíṣe. Kò sí ìdàgbàsókè tí ará tàbí èmi láìsí ìgbìyànjú, àti àwọn ìgbìyànjú túmọ̀ sí iṣẹ́.
Olórí tí ó ṣetán láti tẹ́tísí ohun tí ọ̀pọ̀ ènìyàn nfẹ́ nílò àtìlẹ́yìn tó gbọn-ń-gbọ́n láti lè ṣe àwọn ohun tí à ń fẹ́ .
Èyin Olùdìbò, A gbọ́dọ̀ pe ara wa padà sí lórí ọ̀nà nípasẹ̀ òmìnira, ìdìbò fún L&K jẹ́ ìbò fún ìdàgbàsókè, Ìgbé dìde àti ìdúróṣinṣin.
Darapọ̀ mọ́ ẹni tó ká júẹ̀, ṣe àtìlẹ́yìn fún ènìyàn tí ọ̀pọ̀ ènìyàn ń-fẹ́, dìbò fún
( *HON LUKMAN MUDASHIR KAYODE* ) gẹ́gẹ́ bi Asojú
IWO/OLAOLUWA/AYEDIRE FEDERAL CONSTITUENCY sí ilé ìgbìmọ̀ asojú sòfin ní Àbújá
L&K DÉÉ ÌRỌ̀RÙN DÉÉ
L&K DÈÈ ÌTÈSÍWÁJÚ DÉÉ
Fún ìtèsíwájú Ayíwọlá dìbò fún L&K ní
2️⃣0️⃣2️⃣3️⃣
L&K MEDIA TEAM🎤🎤

Comments